Jẹnẹsisi 31:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ní àkókò tí àwọn ẹran náà ń gùn, mo rí i lójú àlá pé àwọn òbúkọ tí wọn ń gun àwọn ẹran jẹ́ àwọn tí àwọ̀ wọn dàbí ti adíkálà ati àwọn onífunfun tóótòòtóó ati àwọn abilà.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:4-15