Jẹnẹsisi 31:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu gbọ́ pé àwọn ọmọ Labani ń sọ pé òun ti gba gbogbo ohun tíí ṣe ti baba wọn, ninu ohun ìní baba wọn ni òun sì ti kó gbogbo ọrọ̀ òun jọ.

Jẹnẹsisi 31

Jẹnẹsisi 31:1-3