Jẹnẹsisi 30:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Rakẹli bá sọ pé, “Ìjàkadì gidi ni mo bá ẹ̀gbọ́n mi jà, mo sì ṣẹgun,” ó sì sọ ọmọ náà ní Nafutali.

Jẹnẹsisi 30

Jẹnẹsisi 30:2-15