Jẹnẹsisi 30:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wí pé, “Ọlọrun ti mú ẹ̀gàn mi kúrò,” ó sọ ọmọ náà ní Josẹfu; ó ní, “Kí OLUWA má ṣàì fún mi ní ọmọkunrin mìíràn.”

Jẹnẹsisi 30

Jẹnẹsisi 30:17-29