Jẹnẹsisi 30:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà ni Ọlọrun ranti Rakẹli, ó gbọ́ ẹ̀bẹ̀ rẹ̀, ó sì ṣí inú rẹ̀.

Jẹnẹsisi 30

Jẹnẹsisi 30:20-26