Jẹnẹsisi 30:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú bí Jakọbu pupọ sí ọ̀rọ̀ tí Rakẹli sọ, ó dá a lóhùn pé, “Ṣé èmi ni Ọlọrun tí kò fún ọ lọ́mọ ni?”

Jẹnẹsisi 30

Jẹnẹsisi 30:1-3