Jẹnẹsisi 30:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Lea bá ní, “Mo láyọ̀, nítorí pé àwọn obinrin yóo máa pè mí ní Ẹni-Ayọ̀,” nítorí náà ó sọ ọmọ náà ní Aṣeri.

Jẹnẹsisi 30

Jẹnẹsisi 30:3-15