Jẹnẹsisi 3:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ojú àwọn mejeeji bá là, wọ́n sì mọ̀ pé ìhòòhò ni àwọn wà, wọ́n bá gán ewé ọ̀pọ̀tọ́ pọ̀, wọ́n sán an mọ́ ìdí.

Jẹnẹsisi 3

Jẹnẹsisi 3:3-9