Jẹnẹsisi 3:15 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo dá ọ̀tá sí ààrin ìwọ ati obinrin náà,ati sí ààrin atọmọdọmọ rẹ ati atọmọdọmọ rẹ̀.Wọn óo máa fọ́ ọ lórí,ìwọ náà óo sì máa bù wọ́n ní gìgísẹ̀ jẹ.”

Jẹnẹsisi 3

Jẹnẹsisi 3:8-24