Jẹnẹsisi 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ejò jẹ́ alárèékérekè ju gbogbo ẹranko tí OLUWA Ọlọrun dá lọ. Ejò bi obinrin náà pé, “Ngbọ́! Ṣé nítòótọ́ ni Ọlọrun sọ pé ẹ kò gbọdọ̀ jẹ ninu èso àwọn igi ọgbà yìí?”

Jẹnẹsisi 3

Jẹnẹsisi 3:1-11