Jẹnẹsisi 29:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí OLUWA rí i pé Jakọbu kò fẹ́ràn Lea, ó fún Lea ní ọmọ bí, ṣugbọn Rakẹli yàgàn.

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:26-35