Jẹnẹsisi 29:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di òwúrọ̀, Jakọbu rí i pé Lea ni wọ́n mú wá fún òun. Ó bi Labani, ó ní, “Irú kí ni o ṣe sí mi yìí? Ṣebí nítorí Rakẹli ni mo fi sìn ọ́? Èéṣe tí o tàn mí jẹ?”

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:19-27