Jẹnẹsisi 29:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jakọbu rí Rakẹli, ọmọ Labani, tíí ṣe arakunrin ìyá rẹ̀, ati agbo aguntan Labani, ó yí òkúta náà kúrò lẹ́nu kànga, ó sì pọn omi fún wọn.

Jẹnẹsisi 29

Jẹnẹsisi 29:9-14