Jẹnẹsisi 28:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà Esau lọ sọ́dọ̀ Iṣimaeli ọmọ Abrahamu, ó sì fẹ́ Mahalati ọmọ rẹ̀, tíí ṣe arabinrin Nebaiotu, ó fi kún àwọn aya tí ó ti ní.

Jẹnẹsisi 28

Jẹnẹsisi 28:5-16