Jẹnẹsisi 28:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Esau rí i pé Isaaki ti súre fún Jakọbu, ó sì ti rán an lọ sí Padani-aramu kí ó lọ fẹ́ iyawo, ati pé nígbà tí ó ń súre fún un, ó pàṣẹ fún un pé kò gbọdọ̀ fẹ́ ninu àwọn ọmọbinrin ará Kenaani.

Jẹnẹsisi 28

Jẹnẹsisi 28:1-7