Jẹnẹsisi 28:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Òkúta tí mo sì gbé nàró bí ọ̀wọ̀n yìí yóo di ilé Ọlọrun, n óo sì fún ìwọ Ọlọrun ní ìdámẹ́wàá ohun gbogbo tí o bá fún mi.”

Jẹnẹsisi 28

Jẹnẹsisi 28:15-22