Jẹnẹsisi 28:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Dìde, lọ sí ilé Betueli, baba ìyá rẹ, ní Padani-aramu, kí o sì fẹ́ ọ̀kan ninu àwọn ọmọ Labani, arakunrin ìyá rẹ.

Jẹnẹsisi 28

Jẹnẹsisi 28:1-7