Jẹnẹsisi 28:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jakọbu tají ní ojú oorun rẹ̀, ó ní, “Dájúdájú OLUWA ń bẹ níhìn-ín, n kò sì mọ̀!”

Jẹnẹsisi 28

Jẹnẹsisi 28:10-17