Jẹnẹsisi 28:13 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA pàápàá dúró lókè rẹ̀, ó wí fún un pé, “Èmi ni OLUWA Ọlọrun Abrahamu baba rẹ ati Ọlọrun Isaaki, ilẹ̀ tí o dùbúlẹ̀ sí yìí, ìwọ ati àwọn ọmọ rẹ ni n óo fi fún.

Jẹnẹsisi 28

Jẹnẹsisi 28:7-15