Jẹnẹsisi 27:45 BIBELI MIMỌ (BM)

tí inú rẹ̀ yóo yọ́, tí yóo sì gbàgbé ohun tí o ti ṣe sí i, n óo wá ranṣẹ pè ọ́ pada nígbà náà. Mo ha gbọdọ̀ ṣọ̀fọ̀ ẹ̀yin mejeeji lọ́jọ́ kan náà bí?”

Jẹnẹsisi 27

Jẹnẹsisi 27:40-46