Jẹnẹsisi 27:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí irú ìre tí baba wọn sú fún Esau yìí ni Esau ṣe kórìíra Jakọbu. Esau dá ara rẹ̀ lọ́kàn le ó ní, “Ìgbà mélòó ni ó kù tí baba wa yóo fi kú? Bí ó bá ti kú ni n óo pa Jakọbu, arakunrin mi.”

Jẹnẹsisi 27

Jẹnẹsisi 27:33-46