Jẹnẹsisi 27:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Isaaki, baba rẹ̀, dá a lóhùn, ó ní,“Níbi tí ilẹ̀ kò ti lọ́ràá ni o óo máa gbé,níbi tí kò sí ìrì ọ̀run.

Jẹnẹsisi 27

Jẹnẹsisi 27:32-40