Jẹnẹsisi 27:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Isaaki baba rẹ̀ bá pè é ó ní, “Súnmọ́ mi, ọmọ mi, kí o sì fi ẹnu kò mí lẹ́nu.”

Jẹnẹsisi 27

Jẹnẹsisi 27:21-27