Jẹnẹsisi 27:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sì dá Jakọbu mọ̀, nítorí pé ọwọ́ rẹ̀ ní irun bíi ti Esau ẹ̀gbọ́n rẹ̀, ó bá súre fún un.

Jẹnẹsisi 27

Jẹnẹsisi 27:17-27