Jẹnẹsisi 27:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu dá baba rẹ̀ lóhùn, ó ní, “Èmi Esau, àkọ́bí rẹ ni, mo ti ṣe bí o ti wí, dìde jókòó, kí o sì jẹ ninu ẹran ìgbẹ́ tí mo pa, kí o lè súre fún mi.”

Jẹnẹsisi 27

Jẹnẹsisi 27:13-24