Jẹnẹsisi 27:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣeéṣe kí baba mi fi ọwọ́ pa mí lára, yóo wá dàbí ẹni pé mo wá fi ṣe ẹlẹ́yà. Nípa bẹ́ẹ̀ n óo fa ègún sórí ara mi dípò ìre.”

Jẹnẹsisi 27

Jẹnẹsisi 27:6-18