Jẹnẹsisi 26:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ kan, lẹ́yìn tí Isaaki ti ń gbé ìlú náà fún ìgbà pípẹ́, Abimeleki, ọba àwọn ará ìlú Filistia yọjú lójú fèrèsé ààfin rẹ̀, ó rí i tí Isaaki ati Rebeka ń tage.

Jẹnẹsisi 26

Jẹnẹsisi 26:6-10