Jẹnẹsisi 26:4 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo sọ àwọn ọmọ rẹ di pupọ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run, n óo sì fún wọn ní ilẹ̀ wọnyi. Nípasẹ̀ wọn ni n óo bukun gbogbo orílẹ̀-èdè ayé,

Jẹnẹsisi 26

Jẹnẹsisi 26:2-5