Jẹnẹsisi 26:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dáhùn pé, “A rí i dájú pé OLUWA wà pẹlu rẹ, ni a bá rò pé, ó yẹ kí àdéhùn wà láàrin wa, kí á sì bá ọ dá majẹmu,

Jẹnẹsisi 26

Jẹnẹsisi 26:24-32