Jẹnẹsisi 26:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá tẹ́ pẹpẹ kan níbẹ̀, ó sì sin OLUWA. Níbẹ̀ ni ó pàgọ́ rẹ̀ sí, àwọn iranṣẹ rẹ̀ sì gbẹ́ kànga kan sibẹ.

Jẹnẹsisi 26

Jẹnẹsisi 26:18-28