Jẹnẹsisi 26:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo kànga tí àwọn iranṣẹ Abrahamu baba rẹ̀ gbẹ́ ní àkókò tí Abrahamu wà láyé ni àwọn ará Filistia rọ́ yẹ̀ẹ̀pẹ̀ dí.

Jẹnẹsisi 26

Jẹnẹsisi 26:12-25