Jẹnẹsisi 26:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà Abimeleki kìlọ̀ fún gbogbo àwọn eniyan rẹ̀ pé, “Ẹnikẹ́ni tí ó bá fi ọwọ́ kan ọkunrin yìí tabi aya rẹ̀, pípa ni wọn yóo pa á.”

Jẹnẹsisi 26

Jẹnẹsisi 26:2-15