Jẹnẹsisi 25:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ rẹ̀, Isaaki ati Iṣimaeli, sin òkú rẹ̀ sinu ihò òkúta Makipela, ninu pápá Efuroni, ọmọ Sohari, ará Hiti, níwájú Mamure.

Jẹnẹsisi 25

Jẹnẹsisi 25:4-15