Jẹnẹsisi 25:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Jakọbu dáhùn pé, “Kọ́kọ́ búra fún mi ná.” Esau bá búra fún Jakọbu, ó sì ṣe bẹ́ẹ̀ gbé ipò àgbà fún un.

Jẹnẹsisi 25

Jẹnẹsisi 25:28-34