Jẹnẹsisi 25:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Esau sọ fún Jakọbu pé, “Jọ̀wọ́ fún mi jẹ ninu ẹ̀bẹ tí ó pupa yìí nítorí pé ebi ń pa mí kú lọ.” (Nítorí ọ̀rọ̀ yìí ni wọ́n ṣe ń pè é ní Edomu.)

Jẹnẹsisi 25

Jẹnẹsisi 25:25-34