Jẹnẹsisi 25:23 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí fún un pé,“Orílẹ̀-èdè meji ni ó wà ninu rẹ,a óo sì pín àwọn oríṣìí eniyan meji tí o óo bí níyà,ọ̀kan yóo lágbára ju ekeji lọ,èyí ẹ̀gbọ́n ni yóo sì máa sin àbúrò.”

Jẹnẹsisi 25

Jẹnẹsisi 25:13-33