Jẹnẹsisi 24:63 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kan, ó lọ ṣe àṣàrò ninu pápá, ojú tí ó gbé sókè, ó rí i tí àwọn ràkúnmí ń bọ̀.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:59-65