Jẹnẹsisi 24:61 BIBELI MIMỌ (BM)

Rebeka ati àwọn iranṣẹbinrin rẹ̀ bá gun ràkúnmí, wọ́n tẹ̀lé ọkunrin náà. Bẹ́ẹ̀ ni iranṣẹ náà ṣe mú Rebeka lọ.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:60-63