Jẹnẹsisi 24:57 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dáhùn pé, “Ẹ jẹ́ kí á kúkú pe omidan náà kí á bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀.”

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:51-58