Jẹnẹsisi 24:50 BIBELI MIMỌ (BM)

Labani ati Betueli dáhùn pé, “Ati ọ̀dọ̀ OLUWA ni nǹkan yìí ti wá, àwa kò sì ní sọ pé bẹ́ẹ̀ ni tabi bẹ́ẹ̀ kọ́.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:40-54