Jẹnẹsisi 24:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni mo tẹríba, mo sì sin OLUWA, mo yin OLUWA Ọlọrun Abrahamu, oluwa mi lógo, ẹni tí ó tọ́ mi sí ọ̀nà tààrà láti wá fẹ́ ọmọ ẹbí oluwa mi fún ọmọ rẹ̀.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:42-52