Jẹnẹsisi 24:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Sara, aya oluwa mi bí ọmọkunrin kan fún un lẹ́yìn tí ó ti di arúgbó, ọmọ yìí sì ni oluwa mi fi ohun gbogbo tí ó ní fún.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:29-41