Jẹnẹsisi 24:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Labani sọ fún un pé, “Jẹ́ kí á lọ sí ilé, ìwọ ẹni tí OLUWA bukun. Èéṣe tí o fi dúró níta gbangba? Mo ti tọ́jú ilé, mo sì ti pèsè ààyè sílẹ̀ fún àwọn ràkúnmí rẹ.”

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:27-35