Jẹnẹsisi 24:3 BIBELI MIMỌ (BM)

n óo sì mú kí o búra ní orúkọ OLUWA Ọlọrun ọ̀run ati ayé, pé o kò ní fẹ́ aya fún ọmọ mi lára àwọn ọmọbinrin ará Kenaani tí mò ń gbé,

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:1-10