Jẹnẹsisi 24:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Rebeka ní arakunrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Labani. Labani yìí ni ó sáré lọ bá ọkunrin náà ní ìdí kànga.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:25-36