Jẹnẹsisi 24:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó bi í pé, “Jọ̀wọ́, kí ni orúkọ baba rẹ? Ǹjẹ́ ààyè ṣì wà ní ilé yín tí a lè wọ̀ sí ní alẹ́ yìí?”

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:18-24