Jẹnẹsisi 24:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ó tó dákẹ́ adura rẹ̀ ni Rebeka ọmọ Betueli yọ sí i pẹlu ìkòkò omi ní èjìká rẹ̀. Ọmọ Nahori ni Betueli jẹ́, tí Milika bí fún un. Nahori yìí jẹ́ arakunrin Abrahamu.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:9-18