Jẹnẹsisi 24:12 BIBELI MIMỌ (BM)

ó sì gbadura báyìí pé “Ìwọ OLUWA Ọlọrun Abrahamu, oluwa mi, jọ̀wọ́, ṣe ọ̀nà mi ní rere lónìí, kí o sì fi ìfẹ́ ńlá rẹ tí kì í yẹ̀ hàn sí Abrahamu, oluwa mi.

Jẹnẹsisi 24

Jẹnẹsisi 24:3-13