Jẹnẹsisi 23:4 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àlejò ni mo jẹ́ láàrin yín, ẹ bá mi wá ilẹ̀ ní ìwọ̀nba ninu ilẹ̀ yín tí mo lè máa lò bí itẹ́ òkú, kí n lè sin òkú aya mi yìí, kí ó kúrò nílẹ̀.”

Jẹnẹsisi 23

Jẹnẹsisi 23:1-14