Jẹnẹsisi 23:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Efuroni alára wà ní ìjókòó pẹlu àwọn ará Hiti yòókù, lójú gbogbo àwọn ará ìlú náà ni ó ti dá Abrahamu lóhùn, ó ní,

Jẹnẹsisi 23

Jẹnẹsisi 23:3-11